Home ÀKỌ̀TUN Àní kò sí e̩ni tó ní àrùn covid-19 ní Kogi – Yahaya Bello
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - May 28, 2020

Àní kò sí e̩ni tó ní àrùn covid-19 ní Kogi – Yahaya Bello

Àní kò sí e̩ni tó ní àrùn covid-19 ní Kogi- Yahaya Bello
Ìròyìn láti o̩wó̩ Yínká Àlàbí

Lati ipari osu keji ti ajakale arun coronavirus ti wo orileede yii ni o ti bere si nii rin wo ipinle ni okookan.
Titi di asiko ti a n ko iroyin yii jo, ipinle Kogi ati Cross Rivers nikan ni arun yii ko raaye wo ninu ipinle merindinlogoji ati oluulu tii se Abuja.
Ale ana ni esi ajo PTF ati ti NCDC tun jade bi o se maa n jade pe ipinle Kogi naa ti darapo mo awon to ni arun naa. Won ni pelu ayewo, eniyan meji ti ko arun naa.
Gomina Yahaya Bello ti ipinle naa ni ki awon araye ma se fi oro kuro ko oun lorun. O ni oun ko gba esi naa wole rara. O ni pelu iwadii oun, ko tii si eni to ni arun naa ni ipinle Kogi.
Ipinle Kogi ni a kii fa ori leyin olori,won ni o ye ki ajo naa pe awon eleto ilera dani bi won se n se ayewo naa.
Ijoba ipinle Kogi ni ojoro patapata ni eleyii. Ajo NCDC ni awon ko mo itumo ojoro inu ayewo naa, won ni bi awon se n se ni awon ipinle to ku naa ni awon se ni Kogi.
Ajo naa ni bi awon kan se n paro nipa arabinrin kan ni ipinle Benue naa laipe yii, ti won si ni ki awon fi esi naa ranse si ibomiran. Ajo naa ni esi ti awon ri naa ni ile iwosan naa ri.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí Orílẹ̀ yìí gba ọlọ́pàá síi, kí á pèsè ohun ààbò ogun tiwantiwa–Ọsinbajo

Ó yẹ kí Orílẹ̀ yìí gba ọlọ́pàá síi, kí á pèsè ohun ààbò ogun tiwantiwa–Ọsinbajo Ọrẹ …