Home ÀKỌ̀TUN Àjo̩ NCDC mú mé̩ta nínú oògùn ìbíle̩ fún ìwòsàn covid-19
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - May 27, 2020

Àjo̩ NCDC mú mé̩ta nínú oògùn ìbíle̩ fún ìwòsàn covid-19

Àjo̩ NCDC mú mé̩ta nínú oògùn ìbíle̩ fún ìwòsàn covid-19
Yínká Àlàbí

Ajakale arun ti gbogbo eniyan ro pe ko ni pe fi orileede yii sile, lo ti ko ti ko lo mo yii. Eyi lo wa bere si ni ko gbogbo aye lominu paapaa orileede Naijiria.
Awon ajo NCDC to n gbogun ti arun coronavirus pokan po lati wo bi won se le fi owo ile too.
Ajo awon onisegun ibile parapo, won sin pa itu meje ti ode n pa ninu igbo pelu egboogi won. Won salaye re replete, ninu eyi ti alaye re ye gbogbo awon ajo yii ni won ti mu meta ninu won.
Iwadii to gbopan si n lo lowo bayii lori awon meta ti won mu fun iwosan arun covid-19.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí Orílẹ̀ yìí gba ọlọ́pàá síi, kí á pèsè ohun ààbò ogun tiwantiwa–Ọsinbajo

Ó yẹ kí Orílẹ̀ yìí gba ọlọ́pàá síi, kí á pèsè ohun ààbò ogun tiwantiwa–Ọsinbajo Ọrẹ …