Home ÀKỌ̀TUN O̩mo̩ Naijiria 265 wò̩lú láti Dubai
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - May 6, 2020

O̩mo̩ Naijiria 265 wò̩lú láti Dubai

O̩mo̩ Naijiria 256 wò̩lú láti Dubai
Ìròyìn láti o̩wó̩ Yínká Àlàbí

Lati igba ti ajakale arun coronavirus ti bere ni awon to ba wu lati pada si orileede won ti n palemo ti won si n ranse si awon alase orileede won.
Eyi naa lo sele si awon omo Naijiria to n gbe ni orileede Dubai ti won ko ara won jo ti won si finu findo pe Naijiria pe ile labo isinmi oko.
Awon nikan ko ni won maa se eleyii, awon orileede bii USA,London ati awon orileede nla lagbaye ni won ti wa palemo awon eniyan won to fe pada sile.
Awon omo Naijiria ti Dubai yii ko ba tile ti de si ilu Eko ni aago meta osan sugbon alaboyun kan bimo si inu baluu naa ni eyi ti o mu ki baluu naa tete pada si Dubai nigba ti won rii pe agbara awon ko fe kaa. Bi arabinrin naa se gbadun pelu omo re ni won bere irinajo won. Won gunle layo si ilu Eko ni nnkan bii aago mejo ku iseju meedogun ale yii.
Bi awon eniyan yii se de, owo ijoba apapo ni won de si, won ko gba won laaye lati darapo mo ebi won bayii titi ti won fi maa yege ayewo arun covid-19.
Gbogbo alaye yii waye gege bi arabinrin Abike Dabiri Erewa se salaye fun awon oniroyin ni oni. Abike Dabiri yii ni Seneto to soju awon omo Naijiria ni eyin odi. Oun naa lo si seto bi awon omo Naijiria marunlelotalerugba (265) to de laipe yii.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ìyá Rainbow ṣọjóòbí, ó ní ẹ̀bẹ̀ pàtàkì kan lòun n bẹ Ọlọ́run

Ìyá Rainbow ṣọjóòbí, ó ní ẹ̀bẹ̀ pàtàkì kan lòun n bẹ Ọlọ́run Ọrẹ Òtítọ́jù Ayẹyẹ ọjọ́ọ̀bì à…