Home ÀKỌ̀TUN Covid-19 soró ní ìdílé Dokpesi
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - May 2, 2020

Covid-19 soró ní ìdílé Dokpesi

Covid-19 soró ní ìdílé Dokpesi
Ìròyìn láti o̩wó̩ Yínká Àlàbí

Ajakale arun coronavirus yari lati gbebe araye. N se ni arun buruku yii tun be gija wo ile oludasile ile-ise Radio Ray power ati telifison AIT.
Leyin ayewo, Oga patapata ile-ise naa Oloye agba Raymond Dokpesi ati eniyan mefa miiran ni arun naa fowoba.
Ki Eledua ba kase arun naa nile lagbaye.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn wọ̀nyí ti kékeré dèrò ẹ̀wọ̀n, jìbìtì orí ayélujára ló kó bá wọn

Àwọn wọ̀nyí ti kékeré dèrò ẹ̀wọ̀n, jìbìtì orí ayélujára ló kó bá wọn Ọrẹ Òtítọ́jù Àwọn ló …