Home ÀKỌ̀TUN Atiku dá òsìsé̩ mé̩rìndínláàdó̩ta dúró
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - May 2, 2020

Atiku dá òsìsé̩ mé̩rìndínláàdó̩ta dúró

Atiku dá òsìsé̩ mé̩rìndínláàdó̩ta dúró
Ìròyìn láti o̩wó̩ Yínká Àlàbí

“Oro kanle kan baale, yoo kan jeje ni mo jokoo mi”. Ajakale arun yii lo si n ja kaakiri to n so eni to nise di alainise lowo mo.
Ohun lo da ebi si opo idile, opo idile lo wa ni orileede yii to je wi pe ori ko ru enu ko je ni won fi n lo iģbesi aye won.
Arun buruku yii ti so won di eni to n kawo bo itan lojoojumo. Eyi naa lo faa ti igbakeji Aare tele ri ni orileede yii, Alhaji Atiku Abubakar fi da osise ile-ise iroyin Gotel Communications re merindinlaadota duro.
Won ni owo osu won gan-an ti n se sege-sege tele naa. Igba ti ko tile wa tun si ise mo bayii wa je ko nira fun oga lati san owo won.
Okan ninu awon oga ileese naa, Alhaji Mohammed El-Yakub ni o fowo si iwe idaduro naa. Ileese naa wa ni ilu Yola ni ipinle Adamawa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Jàndùkú ya wọ iléeṣẹ́ rédíò Amúlùúdùn n’Íbàdàn, wọ́n ba ọ̀pọ̀ dúkìá jẹ́

Jàndùkú ya wọ iléeṣẹ́ rédíò Amúlùúdùn n’Íbàdàn, wọ́n ba ọ̀pọ̀ dúkìá jẹ́ Ọrẹ Òtítọ́jù Òkú k…