Home ÀKỌ̀TUN Èmi àti Olure̩mi yege àjàkálè̩ àrùn covid-19…..Tinubu
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - April 28, 2020

Èmi àti Olure̩mi yege àjàkálè̩ àrùn covid-19…..Tinubu

Èmi àti Olure̩mi yege àjàkálè̩ àrùn covid-19…..Tinubu
Láti o̩wó̩ Yínká Àlàbí

Asiwaju agba fun egbe oselu APC, Asiwaju Bola Ahmmed Tinubu ni oun ko ni arun ajakale coronavirus bi gbogbo eniyan se n gbee poori enu. O ni awon kan ni oun ti wa ni igbele olojo merinla pelu Oluremi. Awon kan tile ni oun ti ko aisan naa ni eyi ti o mu ki oun ati Oluremi se ayewo arun naa.
Asiwaju ni ko je dandan pe ti eni to ba wa ni egbe eniyan ba ni arun, eni naa gbodo nii.
O ni awuyewuye yii gbile nigba ti awon eniyan gbo iku olori eso oun, Lati Raheem ti o file saso bora leyin aisan ranpe.
Asiwaju ni Lati Raheem je eda kan ti ko ki n fi ara re sere rara, bi o se mo pe o te oun die ni o ti gba ile iwosan lo, o kan je wi pe aisan lo se wo ko si eni to ri ti olojo se.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn wọ̀nyí ti kékeré dèrò ẹ̀wọ̀n, jìbìtì orí ayélujára ló kó bá wọn

Àwọn wọ̀nyí ti kékeré dèrò ẹ̀wọ̀n, jìbìtì orí ayélujára ló kó bá wọn Ọrẹ Òtítọ́jù Àwọn ló …