Home ÀKỌ̀TUN Ìròyìn léréfèé lórí ò̩rò̩ tì Ààre̩ Buhari bá ará ìlú so̩ lálé̩ òní
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - April 27, 2020

Ìròyìn léréfèé lórí ò̩rò̩ tì Ààre̩ Buhari bá ará ìlú so̩ lálé̩ òní

Ìròyìn léréfèé lórí ò̩rò̩ tì Ààre̩ Buhari bá ará ìlú so̩ lálé̩ òní
Láti o̩wc´ Yínká Àlàbí

Isede si n te siwaju ni ipinle Eko, Ogun ati Abuja. Ose kan gbako ni Aare Buhari fi kun isede to ti bere lati ose merin seyin.
Isede naa maa de die lati ojo kerin osu to n bo, aaye lati jade maa wa ni awon ojo kookan.
Nitori oro aje ilu, awon ileese Kan maa bere ise lati aago mesan-an titi di mefa irole.
Isede gidi maa bere lati ale ni aago mejo titi di mefa owuro ojo keji.
Ofin to de awon ero bii ti ile ijo, Soosi ati Mosalasi si wa nibe.
Ko gbodo si irinajo lati ipinle kan si ekeji ninu isede naa.
Kano bere ofin konile-o-gbele fun ose meji gbako.

Check Also

Ilé ẹjọ́ tú el-zakzaky àti ìyàwó rẹ̀ sílẹ̀

Ilé ẹjọ́ tú el-zakzaky àti ìyàwó rẹ̀ sílẹ̀ Fẹ́mi Akínṣọlá Ajá tó relé ẹkùn tó bọ̀,ó tọ́ kí…