Home ÀKỌ̀TUN Ìjo̩ba àpapò̩ fo̩wó̩ ye̩pe̩re̩ mú ìpínlè̩ Kano lórí covid-19 … Gaduje
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - April 27, 2020

Ìjo̩ba àpapò̩ fo̩wó̩ ye̩pe̩re̩ mú ìpínlè̩ Kano lórí covid-19 … Gaduje

Ìjo̩ba àpapò̩ fo̩wó̩ ye̩pe̩re̩ mú ìpínlè̩ Kano lórí covid-19… Gaduje
Ìròyìn láti s̩wo̩ Yínká Àlàbí

Gomina ipinle Kano, Alhaji Abdullahi Ganduje lo n forere yii ni ori redio BBC ti ede Hausa ni oni ojo Aje.
O ni ajo ti ijoba apapo gbe kale lori ajakale arun covid-19 n gbiyanju kaakiri orileede sugbon won fi owo yepere mu ipinle Kano.
O ni gbogbo awon to wa ninu ajo yii ni won mo pe wahala wa ni ipinle Kano, o ni koda olori ajo naa Alagba Boss Mustapha sun orun ojo kan ni ipinle naa, sibe ko si iyato gidi.
O ni isoro awon koko bere lori ero ti o n se ayewo bi eniyan ba ni arun naa tabi ko nii.
Gomina ni ero naa ko se ra loja ni boya ijoba ipinle naa ko ba ti binu ra die. O ni awon ko tii so ireti nu nitoŕi pe Minisita eto ilera lorileede yii Dokita Osagie Ehanire se ileri pe ero naa maa de ipinle kano ni oni ti o si maa bere ise.
Gomina ni lenu ojo meloo kan, awon to ni arun naa ti pe metadinlogorin ni eyi to buru jojo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ọwọ́ pálábá adigunjalè ẹlẹ́nimẹ́ta tó ja Tọpẹ Alabi lólè owó ṣégi

Ọwọ́ pálábá adigunjalè ẹlẹ́nimẹ́ta tó ja Tọpẹ Alabi lólè owó ṣégi Ọrẹ Òtítọ́jù Ọjọ́ gbogbo…