Home ÀKỌ̀TUN Ẹnìkejì ti kú nítorí àrùn apinni léèmí Coronavirus ní Ọ̀yọ́
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - April 27, 2020

Ẹnìkejì ti kú nítorí àrùn apinni léèmí Coronavirus ní Ọ̀yọ́

Ẹnìkejì ti kú nítorí àrùn apinni léèmí Coronavirus ní Ọ̀yọ́

Fẹ́mi Akínṣọlá

Ikú kìí se ẹgbẹ́ àrùn o. Àrùn ló se é wò,a ò rí ti ọlọ́jọ́ se.
Ìjọba ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ti kéde pé ó ti di ẹni méjì tó kú báyìí nítorí àrùn apinni léèmí Coronavirus ní ìpínlẹ̀ náà.

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ , onímọ Ẹ̀rọ Ṣèyí Mákindé ló kéde rẹ̀ lórí ẹ̀rọ ìkànnì abẹ́yefò Twitter ní Ọjọ́ Àìkú.

Gómìnà náà ní ẹni tókú náà wà lára àwọn tí àyẹ̀wò ṣẹṣẹ fihàn pé wọ́n ní àrùn apinni léèmí Coronavirus.

Bẹ́ẹ̀ ni Gómìnà náà fikún un pé ènìyàn mọ́kànlélógún ló ti ní àrùn náà nípìńlẹ̀ náà, àmọ́ ènìyàn mẹ́jọ nínú wọn ló ń gba ìtọ́jú lọ́wọ́lọ́wọ́.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ìyá Rainbow ṣọjóòbí, ó ní ẹ̀bẹ̀ pàtàkì kan lòun n bẹ Ọlọ́run

Ìyá Rainbow ṣọjóòbí, ó ní ẹ̀bẹ̀ pàtàkì kan lòun n bẹ Ọlọ́run Ọrẹ Òtítọ́jù Ayẹyẹ ọjọ́ọ̀bì à…