Home ÀKỌ̀TUN Covid-19 kò dá ààwè̩ gbígbà dúró – Aare Buhari
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - April 24, 2020

Covid-19 kò dá ààwè̩ gbígbà dúró – Aare Buhari

ccm, kò dá ààwè̩ gbígbà dúró – Aare Buhari
Ìròyìn láti o̩wó̩ Yínlá Àlàbí

Aare Mohammadu Buhari to je Aare orileede yi lo n ki awon Musulumi ku odun aawe to bere ni oni ojo kerindinlogbon osu kerin Odin 2020.
O ni ki a ma titori ajakale arun coronavirus to n ba wa ja lati osu keji seyin fi aawe sile.
Aare ni gbogbo Musulumi ti o ba ti ni alaafia ni ko ba wa pawopo gba aawe naa. O ni eyi maa fun gbogbo wa ni agbara lati ba aisan naa ja.
Aare si tun ro gbogbo Musulumi pe ki won se jeje lasiko odun yii. O ni ki gbogbo Musulumi pa ofin esin ati ti ijoba mo nitori anfaani gbogbo wa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Rògbòdìyàn ẹgbẹ́ onímọ́tò Èkó n fẹ́jú kẹkẹ

Rògbòdìyàn ẹgbẹ́ onímọ́tò Èkó n fẹ́jú kẹkẹ Ọrẹ Òtítọ́jù Àwọn àgbà sọ pé ìjàngbọ̀n kìí nìka…