Home ÀKỌ̀TUN Kò sí ohun tó burú pé kí àwa tí a lọ síbi òkú Abba Kyari má wọ Aso Rock- Garba Shehu
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - April 23, 2020

Kò sí ohun tó burú pé kí àwa tí a lọ síbi òkú Abba Kyari má wọ Aso Rock- Garba Shehu

Kò sí ohun tó burú pé kí àwa tí a lọ síbi òkú Abba Kyari má wọ Aso Rock- Garba Shehu

Fẹ́mi Akínṣọlá

Lẹ́yìn gbogbo awuyewuye tí ó rọ̀ mọ́ ètò ìsìnkú olórí àwọn òṣìṣẹ́ níléèjọba ní Àbújá, Abba Kyari ni ọ̀rọ̀ jáde.

Wọ́n sòfin pé gbogbo àwọn tó lọ síbi ètò ìsìnkú náà gbọdọ̀ ya ara wọn sọ́tọ̀ fún ọjọ́ mẹ́rìnlà bí NCDC àti àjọ elétò ìlera WHO ṣé sọ.

Garba Shehu tó jẹ́ agbẹnusọ sí Ààrẹ Buhari wà lára àwọn tí ọ̀rọ̀ náà kàn lásìkò yìí . Ó ṣàlàyé pé ìgbésẹ̀ ‘ Ẹ má wọ inú Ilé Àpáta páàrá agbára “Aso Rock” lásìkò yìí ‘ tọ̀nà dáadáa.

Garba Shehu ní oníkálùkù tó lọ síbi ètò ìsìnkú náà ló gbọ́n mọ pé ìgbésẹ̀ yìí kò burú nítorí ó jẹ́ ọ̀nà láti gbógun ti ìtànkálẹ̀ àrùn apinni léèmí coronavirus yìí.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Adédoyin ṣépè fáwọn oníròyìn nílé ẹjọ́

Adédoyin ṣépè fáwọn oníròyìn nílé ẹjọ́ Ọrẹ Òtítọ́jù Ìyàlẹ́nu ló jẹ́ fáwọn oníròyìn láàárọ̀…