Home ÀKỌ̀TUN Iná àrùn coronavirus tún jò kẹ̀ù ní Nàìjíríà, ènìyàn 117 ló ràn mọ́
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - April 22, 2020

Iná àrùn coronavirus tún jò kẹ̀ù ní Nàìjíríà, ènìyàn 117 ló ràn mọ́

Iná àrùn coronavirus tún jò kẹ̀ù ní Nàìjíríà, ènìyàn 117 ló ràn mọ́

Fẹ́mi Akínṣọlá

Àjọ tó ń gbógun ti àjàkálẹ̀ àrùn ní Nàìjíríà, NCDC ti kéde pé ènìyàn mẹ́tàdínlọ́gọ́fà míràn tún ti ní àrùn Covid-19.

Alẹ́ ọjọ́ Ìṣẹ́gun ni àjọ náà fi Ìkéde yìí síta.

Ní báyìí, ó ti pé ènìyàn 782 tó ti ní àrùn yìí ní Nàìjíríà.

Ènìyàn igba dín mẹ́ta ti rí ìwòsàn, mẹ́ẹ̀dọ́gbọ̀n sì ti kú.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Adédoyin ṣépè fáwọn oníròyìn nílé ẹjọ́

Adédoyin ṣépè fáwọn oníròyìn nílé ẹjọ́ Ọrẹ Òtítọ́jù Ìyàlẹ́nu ló jẹ́ fáwọn oníròyìn láàárọ̀…