Home ÀKỌ̀TUN Báwo ni obìnrin ẹni ọdún 68 ṣe lóyún, bímọ ní ìlú Èkó?
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - April 22, 2020

Báwo ni obìnrin ẹni ọdún 68 ṣe lóyún, bímọ ní ìlú Èkó?

Báwo ni obìnrin ẹni ọdún 68 ṣe lóyún, bímọ ní ìlú Èkó?

Fẹ́mi Akínṣọlá

Arábìnrin ẹni ọdún méjìdínláàdọ́rin kan ti di alábiamọ báyìí ní ìpínlẹ̀ Èkó lẹ́yìn tí wọ́n gbẹ̀bì ìbejì fún un ní iléèwòsàn nlá Fásitì ìlú Èkó, LUTH

ètò ìlóyún ìgbàlódé, IVF ni wọ́n ṣe fún arábìnrin náà tó sì jẹ́ pé ìgbà àkọ́kọ́ nìyí tí yóó finú ṣoyún fi ẹ̀yìn rẹ gb’ọ́mọ pọ̀n.

Alága ìgbìmọ àwọn dókítà, CMAC ní iléèwòsàn ńlá LUTH, Ọ̀jọ̀gbọ́n Wasiu Adeyẹmọ ṣàlàyé pé iṣẹ́ abẹ ní wọ́n fi gbẹ̀bí arábìnrin náà àti pé kìí ṣe inú iléèwòsàn náà ni wọ́n ti ṣètò ìlóyún ìgbàlódé náà ṣùgbọ́n níbẹ̀ ni wọ́n ti ṣe ìtọ́jú arábìnrin ọ̀hún àti oyún rẹ̀ láti ìgbà tí kinní ọ̀hún ti di òhun.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Okorocha ketí ikún sí ìpé làwọn fi ṣígun kàá mọ́lé mọ́lé-EFCC

Wọ́n ní Okorocha ketí ikún sí ìpé làwọn fi ṣígun kàá mọ́lé mọ́lé Ọrẹ Òtítọ́jù Àjọ tó ń gbó…