Home ÀKỌ̀TUN Èmi kò ní àrùn coronavirus – Yahaya Bello
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - April 16, 2020

Èmi kò ní àrùn coronavirus – Yahaya Bello

Èmi kò ní arun coronavirus – Yahaya Bello

Ìròyìn láti o̩wó̩ Yínká Àlàbí

Gomina ipinle Kogi,Ogbeni Yahaya Bollo lo n forere lori ero ayelujara pe ki won se fi orokoro ko oun lorun, oun lo ni arun covid-19 gege bi awon oloselu Kan se n gbee kiri.
O ni loooto ni adari aabo ijoba apapo, Alagba Abba kyari to ni arun naa ba oun lalejo nigba ti o ti orileede Germany de. O ni o wa ba oun kedun iku mama oun. O ni abewo naa ko muu dandan pe oun gbodo ko arun naa. O ni oun nikan ko ni ko ko arun naa lara re, Alhaji Lai Mohammed naa wa lara awon to fi abewo ye ohun si pelu awon eniyan pataki miiran.
Gomina tun wa ro awon oloselu ti won ko mo ju ki won ko owo je lo,o ni ko dara ki won fi arun coronavirus ko owo je rara. O ni asiko to ye ki iberu Olorun wa ju niyi. O ni oun ko si ni gba ki oloselu kankan lo oun lati ko owo je, eyi lo mu ki oun maa forere pe oun ko ni arun coronavirus rara.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Rògbòdìyàn ẹgbẹ́ onímọ́tò Èkó n fẹ́jú kẹkẹ

Rògbòdìyàn ẹgbẹ́ onímọ́tò Èkó n fẹ́jú kẹkẹ Ọrẹ Òtítọ́jù Àwọn àgbà sọ pé ìjàngbọ̀n kìí nìka…