Home ÀKỌ̀TUN Covid 19; Òkú re̩pe̩te̩ ní orí títì Áfíríkà, e̩bo̩ kó padà só̩dò̩ e̩lé̩bo̩…… Fani-Kayode
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - April 13, 2020

Covid 19; Òkú re̩pe̩te̩ ní orí títì Áfíríkà, e̩bo̩ kó padà só̩dò̩ e̩lé̩bo̩…… Fani-Kayode

Covid 19; Òkú re̩pe̩te̩ ní orí títì Áfíríkà, e̩bo̩ kó padà só̩dò̩ e̩lé̩bo̩…… Fani-Kayode
Ìròyìn láti cwó̩ Yìnká Àlàbí

Hun un! Gbogbo bi ile adulawo se n wole adura lori arun buruku coronavirus pe ki o tete kase nile, n se ni aya Bill Gates to wa ninu awon to lowo ju lagbaye ni oun ri oku repete ni ile Afirika.
Eyi bi opo eniyan ninu pe oniriikuri ati onisokuso ni arabinrin naa.
Arabinrin naa, Melinda Gates ni pelu abewo oun si ile Adulawo, awon agbegbe po ti ko ni ina, ti ko ni omi to see mu, bee ni opo ile ko da ile igbonse ni, won ko da ile iwe ni. O ni bawo ni won se wa fe gbe igbe aye ki won jinna si ara won?
O ni bawo ni awon ti won n gbe ile doju doju se fe jinna si ara won nigba ti o je pe ile idana kan, ile iwe kan, ile iyagbe kan naa ni gbogbo won n to si.
Melinda ni bi oun ko tile ranti gbogbo ilu to ku, o ni oun si se iranti abewo oun si orileede Ghana.
Eyi lo ni o mu ki oun so wi pe arun naa maa soro lati tete segun ni ile Afirika.
Ni gbigbona bee ni Minisita fun oko ofurufu tele, Alagba Femi Fani-Kayode tete daa pada. O ni “ki ebo naa ya tete pada si odo elebo,ki asasi pada si odo alasasi..”. Fani-kayode ni Eledua ko ni je ki a ri iru re ni ile Adulawo.
Ori ero ayelujara “Twitter ” ni Fani-Kayode ti tete daa lohun.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Jàndùkú ya wọ iléeṣẹ́ rédíò Amúlùúdùn n’Íbàdàn, wọ́n ba ọ̀pọ̀ dúkìá jẹ́

Jàndùkú ya wọ iléeṣẹ́ rédíò Amúlùúdùn n’Íbàdàn, wọ́n ba ọ̀pọ̀ dúkìá jẹ́ Ọrẹ Òtítọ́jù Òkú k…