Home ÀKỌ̀TUN Buhati fi ò̩s̩è̩ méjì kún ìséde Eko, Ogun ati Abuja
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - April 13, 2020

Buhati fi ò̩s̩è̩ méjì kún ìséde Eko, Ogun ati Abuja

Buhati fi ò̩s̩è̩ méjì kún ìséde Eko, Ogun ati Abuja
Ìròyìn láti o̩wó̩ Yínká Àlàbí

Aare Mohammed Buhari ba gbogbo omo Naijiria soro ni aago meje irole oni. Ara awon koko ibe ni ki omo Naijiria je ki a ni ifarada lori arun covid-19 to n ba gbogbo agbaye ja.
O ni gbogbo inawo ti o ba wa lakata ijoba apapo ni awon maa se lati ma se je ki inira ile gbigbe naa po ju fun awon ara ilu.
O ni pelu gbogbo abo ti o de ori tabili oun lati odo awon ajo to n foju to ajakale naa, a ni afarada to po ni eyi to je ki ijoba apapo fi ose meji kun isede awon ipinle meta ti won bere ni ose meji seyin.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ọwọ́ pálábá adigunjalè ẹlẹ́nimẹ́ta tó ja Tọpẹ Alabi lólè owó ṣégi

Ọwọ́ pálábá adigunjalè ẹlẹ́nimẹ́ta tó ja Tọpẹ Alabi lólè owó ṣégi Ọrẹ Òtítọ́jù Ọjọ́ gbogbo…