Home ÀKỌ̀TUN Ọjọ́ ọdún Àjíǹde ṣe pàtàkì fún àwọn ọmọlẹ́yìn Kírísítì ní a ṣe fẹ́ ṣe ìsìn ní ọjọ́ náà – CAN Ondo
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - April 11, 2020

Ọjọ́ ọdún Àjíǹde ṣe pàtàkì fún àwọn ọmọlẹ́yìn Kírísítì ní a ṣe fẹ́ ṣe ìsìn ní ọjọ́ náà – CAN Ondo

Ọjọ́ ọdún Àjíǹde ṣe pàtàkì fún àwọn ọmọlẹ́yìn Kírísítì ní a ṣe fẹ́ ṣe ẹ̀sín ní ọjọ́ náà – CAN Ondo

Fẹ́mi Akínṣọlá

Àjọ tó ń mójútó ọ̀rọ̀ àwọn ọmọlẹ́yìn Kírísítì ní ìpínlẹ̀ Ondo, CAN ti sọ ìdí tí àwọn ṣe kéde kí àwọn ènìyàn lọ sí ilé ìjọsìn ní ọjọ́ Àjíǹde tí yóó wáyé ní ọjọ́ Ìsinmi ọ̀sẹ̀ yìí.

Alága àjọ náà, Ẹniọ̀wọ̀ Oladapo John lásìkò tó ń bá akọ̀ròyìn ṣọ̀rọ̀ ní Ọjọ́ ọdún Àjinde ṣe pàtàkì fún àwọn ọmọlẹ́yìn Kírísítì ní wọ́n ṣe fẹ́ ṣe isin ní ọjọ́ náà àti pé ọjọ́ náà ni ó jẹ́ òpó Kírísítìẹ́nì.

Ẹniọ̀wọ̀ náà fikún un pé àwọn ti ṣe ìlàkalẹ̀ sílẹ̀ fún àwọn ènìyàn láti fọ ọwọ́ wọn àti kí wọ́n yàgò fún ara wọn lásìkò tí ẹ̀sìn náà bá ń lọ lọ́wọ́.

Bákan náà ni wọ́n fikún wí pé àwọn ní ìgbàgbọ́ pé Ọlọ́run ló le dẹ́kun àjàkálẹ̀ àrùn Coronavirus tó ń jà ràn-ìn káàkiri àgbáyé náà.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí Orílẹ̀ yìí gba ọlọ́pàá síi, kí á pèsè ohun ààbò ogun tiwantiwa–Ọsinbajo

Ó yẹ kí Orílẹ̀ yìí gba ọlọ́pàá síi, kí á pèsè ohun ààbò ogun tiwantiwa–Ọsinbajo Ọrẹ …