Home ÀKỌ̀TUN Ẹlẹ́wọ̀n 2600 ni ìjọba tú sílẹ̀ ní Nàìjíríà nítorí àrùn apinni léèmí Coronavirus
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - April 11, 2020

Ẹlẹ́wọ̀n 2600 ni ìjọba tú sílẹ̀ ní Nàìjíríà nítorí àrùn apinni léèmí Coronavirus

Ẹlẹ́wọ̀n 2600 ni ìjọba tú sílẹ̀ ní Nàìjíríà nítorí àrùn apinni léèmí Coronavirus

Fẹ́mi Akínṣọlá

Ìjọba orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti tú ẹlẹ́wọ́n tó lé ní ẹgbẹ̀rún méjì sílẹ̀ ní ọgbà ẹ̀wọ̀n káàkiri orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.

Aregbesọla ní Ìjọba gbé ìgbésẹ̀ náà láti dẹ́kun ìtànkálẹ̀ àrùn Coronavirus ní Nàìjíríà.

Mínísítà fún ọ̀rọ̀ abẹ́lé lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà náà ni àwọn tí yóó jẹ àǹfààní ìtúsílẹ̀ yìí ni àwọn ẹni tó bá ti kọjá ọgọ́ta ọdún, àwọn aláìsàn , àwọn tó ní àrùn ọpọlọ àti àwọn tó sẹ ẹ̀sẹ̀ kéékèké.

Mínísítà fún ọ̀rọ̀ abẹ́lé lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Rauf Aregbesola ló kéde rẹ̀ ní ibi ayẹyẹ tí wọ́n ti ṣe ìtúsílẹ̀ náà.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ìyá Rainbow ṣọjóòbí, ó ní ẹ̀bẹ̀ pàtàkì kan lòun n bẹ Ọlọ́run

Ìyá Rainbow ṣọjóòbí, ó ní ẹ̀bẹ̀ pàtàkì kan lòun n bẹ Ọlọ́run Ọrẹ Òtítọ́jù Ayẹyẹ ọjọ́ọ̀bì à…