covid 19: Ènìyàn 2,752 ti lùgbàdì coronavirus ní Saudi Arabia
covid 19: Ènìyàn 2,752 ti lùgbàdì coronavirus ní Saudi Arabia
Fẹ́mi Akínṣọlá
Ìjọba ilẹ̀ Saudi ṣàlàyé pé ó ti di èèyàn ẹgbẹ̀rún méjì àti ẹgbẹ̀rin dín díẹ̀ láàdọ́rin èèyàn ti wọ́n ti lùgbàdì àjàkálẹ̀ àrùn apinni léèmí coronavirus tó wà n’íta yìí.
Ìjọba Saudi ni wọ́n ń sa ipá wọ́n láti gbógun ti àrùn yìí bákan náà ní wọ́n ń gbé gbogbo ìgbésẹ̀ tó yẹ láti ran àwọn ará ìlú lọ́wọ́ lásìkò yìí kí ọrùn má baà wọ̀ wọ́n ju bí ó se yẹ lọ bí wọ́n se ń dojúkọ ìpèníjà kòrónáfairọ̀ọ̀sì ní ìlú náà.
Bí ẹgbẹ́ òṣèlú ù mi bá fàmí kalẹ̀, ìyókù sẹ́pẹ́rẹ́—Tinubu
Bí ẹgbẹ́ òṣèlú ù mi bá fàmí kalẹ̀, ìyókù sẹ́pẹ́rẹ́—Tinubu Ọrẹ Òtítọ́jù Olùdíje fún i…