Home ÀKỌ̀TUN Coronavirus: Àwọn òṣìṣẹ elétò ìlera láti China ti dé sí Nàìjíríà báyìí
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - April 9, 2020

Coronavirus: Àwọn òṣìṣẹ elétò ìlera láti China ti dé sí Nàìjíríà báyìí

Coronavirus: Àwọn òṣìṣẹ elétò ìlera láti China ti dé sí Nàìjíríà báyìí

Fẹ́mi Akínṣọlá

Ìkọ àwọn onímọ̀ ìlera láti China ti balẹ sí Nàìjíríà láìpẹ́

Ìròyìn ní ọ̀kan lára àwọn ikọ̀ onímọ ìlera tó n bọ láti orílẹ̀-èdè China sí Nàìjíríà náà ti dé.

Gẹ́gẹ́ bí ohun tá rí kà lójú òpó ayélujára Twitter iléeṣẹ́ alágbàṣe China Civil Engineering Construction Company, àwọn onímọ̀ ìlera yí yóò ṣe ìrànwọ́ f’órílẹ̀ – èdè Nàìjíríà nípa ìtọ́jú àti kíkọjú àjàkálẹ̀ àrùn Coronavirus.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí Orílẹ̀ yìí gba ọlọ́pàá síi, kí á pèsè ohun ààbò ogun tiwantiwa–Ọsinbajo

Ó yẹ kí Orílẹ̀ yìí gba ọlọ́pàá síi, kí á pèsè ohun ààbò ogun tiwantiwa–Ọsinbajo Ọrẹ …