Home ÀKỌ̀TUN Ìjo̩ba àpapò̩ fé̩ pèsè iná ò̩fé̩ osù méjì torí covid -19
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - April 4, 2020

Ìjo̩ba àpapò̩ fé̩ pèsè iná ò̩fé̩ osù méjì torí covid -19

Ìjo̩ba apapo̩ fe̩ pese ina o̩fe̩ osu meji tori covid -19
Ìròyìn láti o̩wo̩ Yínká Àlàbí

Ile igbimo̩ asoju sofin ti n gbimo̩ po̩ lati wa ide̩ra fun ara ilu nitori isoro covid-19 to wa ni ilu. Aisan naa ko je̩ ki oloko ko le r’oko be̩e̩ ni ko je ki olodo o le r’odo.
Inira yii lo je ki awo̩n ara ilu maa pariwo ti ariwo naa si ti ta si wo̩n leti.
Eyi lo je̩ ki wo̩n maa finu konu ti wo̩n si n fi ikun lu ikun fun aba gidi to maa se ara ilu loore.
Wo̩n ni awo̩n fe̩ ki ina ofe̩ naa wa fun osu ke̩rin yii ati osu karun-un gbako.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ìyá Rainbow ṣọjóòbí, ó ní ẹ̀bẹ̀ pàtàkì kan lòun n bẹ Ọlọ́run

Ìyá Rainbow ṣọjóòbí, ó ní ẹ̀bẹ̀ pàtàkì kan lòun n bẹ Ọlọ́run Ọrẹ Òtítọ́jù Ayẹyẹ ọjọ́ọ̀bì à…