Covid -19 gbé ìwòsàn òfé̩ dé Eko
Covid -19 gbé ìwòsàn òfé̩ dé Eko
Ìròyìn láti o̩wó̩ Yìnká Àlàbí
Arun buruku coronavirus to wolu yi ko mo olowo yato si talaka, ni eyi to mu ki ijoba apapo ti gbogbo ipinle̩ me̩ta pa patapata. Iye̩n ipinle̩ Eko, Ogun ati Abuja fun ose̩ meji gbako.
Ìsoro yii ni ijo̩ba ipinle Eko ri pe o po̩ fun awo̩n ara ilu, lo mu ki o so̩ gbogbo ile-iwosan metadinlo̩gbo̩n to wa ni ipinle̩ naa di o̩fe̩.
Gomina Sanwo-Olu ni gbogbo aisan lati ori o̩mo̩ bibi wo̩o̩ro̩wo̩ ati eyi to je̩ pe̩lu ise̩ abe̩ pata ni agbara ijo̩ba ipinle̩ naa ka. O ni eleyii si maa wa be̩e̩ fun gbogbo osu ke̩rin ti a wa yi.
Gomina wa fi asiko naa kilo fun awon kolo̩ro̩si eniyan ti wo̩n si n fagidi jade. O ni o̩wo̩ sinkun ofin ti te̩ irinwo bo̩o̩si ti wo̩n kun ni awo̩ ye̩lo. O ni ijo̩ba si maa fi wo̩n jofin.
Rògbòdìyàn ẹgbẹ́ onímọ́tò Èkó n fẹ́jú kẹkẹ
Rògbòdìyàn ẹgbẹ́ onímọ́tò Èkó n fẹ́jú kẹkẹ Ọrẹ Òtítọ́jù Àwọn àgbà sọ pé ìjàngbọ̀n kìí nìka…