Home ÀKỌ̀TUN Ibi ìpàdé ìtagbangba PDP kó̩ ni Seyi Makinde ti kó coronavirus
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - April 3, 2020

Ibi ìpàdé ìtagbangba PDP kó̩ ni Seyi Makinde ti kó coronavirus

Ibi ìpàdé ìtagbangba PDP kó̩ ni Seyi Makinde ti kó coronavirus
Iroyin lati owo Yinka Alabi.
E wo fidio yii.
Awon omo egbe oselu PDP ni won n da awon egbe oselu APC lohun nigba ti won ju fidio yii de odo awon egbe oselu PDP. Won ni ti o ba je ibi ipade yii ni, elegbe gbogbo awon lo ti maa koo sugbon oro ko ri bee. Nipa idi eyi, won ro awon omo egbe oselu APC pe ki won ye gbe iroyin eleje kiri.

ù

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Bí ẹgbẹ́ òṣèlú ù mi bá fàmí kalẹ̀, ìyókù sẹ́pẹ́rẹ́—Tinubu

Bí ẹgbẹ́ òṣèlú ù mi bá fàmí kalẹ̀, ìyókù sẹ́pẹ́rẹ́—Tinubu Ọrẹ Òtítọ́jù Olùdíje fún i…