Home ÀKỌ̀TUN Ogún ènìyàn jàjà bọ́ lọ́wọ́ coronavirus
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - April 2, 2020

Ogún ènìyàn jàjà bọ́ lọ́wọ́ coronavirus

Ogún ènìyàn jàjà bọ́ lọ́wọ́ coronavirus
Ìròyìn láti ọwọ́ Yínká Àlàbí
Ni ipinle Eko ni ori ti ko ogun eniyan yo ni ile iwosan ti won ti n toju awon ti kokoro Covid-19 n ba ja.
Bi o tile je pe won ni ko si oogun kan gbogi fun aisan naa sugbon Eledua n fun ipinle Eko se lati ni aseyori lori itoju awon alaisan naa. Ti a ko ba gbagbe, arakunrin omo orileede Italy ni o koko gba iwosan naa ki awon meta miiran, marun-un miiran ki mokanla to kun-un ni oni ojo keji, osu kerin odun ti a wa yii.
Ijoba apapo, ipinle ati ibile pelu ajo NCDC ni ki awon eniyan ma se dawo imototo duro ki onikaluku si gbe ile re fun igba die ki arun buruku naa le kase nile patapata.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Jàndùkú ya wọ iléeṣẹ́ rédíò Amúlùúdùn n’Íbàdàn, wọ́n ba ọ̀pọ̀ dúkìá jẹ́

Jàndùkú ya wọ iléeṣẹ́ rédíò Amúlùúdùn n’Íbàdàn, wọ́n ba ọ̀pọ̀ dúkìá jẹ́ Ọrẹ Òtítọ́jù Òkú k…