Home ÀKỌ̀TUN Seyi Makinde di gómìnà kẹ́ta tó kó àrùn Covid-19
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - March 30, 2020

Seyi Makinde di gómìnà kẹ́ta tó kó àrùn Covid-19

Seyi Makinde di gómìnà kẹ́ta tó kó àrùn Covid-19
Ìròyìn láti ọwọ́ Yínká Àlàbí

Oni ogbon ojo, osu keta ni ayewo gomina ipinle Oyo, Alagba Seyi Makinde jade, ti ayewo naa si gbee pe o ni arun naa. Oun ni o maa je eleeketa gomina ni orileede yii ti ayewo fihan pe won ni arun kokoro naa.
Gomina ipinle Bauchi, Bala Mohammmed ni o koko ni, ki ayewo to gbe ti gomina ipinle Kaduna , Nazir El-Rufai jade. Eyi lo mu ki gbogbo eka ijoba maa pariwo ki onile ko gbele nitori ajakale arun naa. Arun naa ko mo olowo, bee ni ko mo talaka. Arun naa ko ni aponle fon egbe oselu to n se ijoba lowo de bi to maa ni fun egbe oselu ti ko se ijoba rara. Bi ojo ni arun naa se n rin, “eni ti eji re ri ni eji n pa”.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Okorocha ketí ikún sí ìpé làwọn fi ṣígun kàá mọ́lé mọ́lé-EFCC

Wọ́n ní Okorocha ketí ikún sí ìpé làwọn fi ṣígun kàá mọ́lé mọ́lé Ọrẹ Òtítọ́jù Àjọ tó ń gbó…