Home ÀKỌ̀TUN Àwọn agbẹjọ́rò ta ko ìnáwó àti òfin kó-nílé-ó-gbélé Ààrẹ àti àwọn gómìnà
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - March 30, 2020

Àwọn agbẹjọ́rò ta ko ìnáwó àti òfin kó-nílé-ó-gbélé Ààrẹ àti àwọn gómìnà

Àwọn agbẹjọ́rò ta ko ìnáwó àti òfin kó-nílé-ó-gbélé Ààrẹ àti àwọn gómìnà
Ìròyìn láti ọwọ́ Yínká Àlàbí

Orisiirisii awon agbejoro ati awon amofin pelu ojogbon lorisiirisii ni won ti n yo suti ete si igbese awon ijoba orileede yii, paapaa julo lori arun coronavirus to gbode.
Won ni ko tile tona rara ki ijoba apapo dede kede ki-onile-o-gbele lai fi to awon ile igbimo asofin kekere ati nla leti. Won ni eleyii lodi patapata si ofin ile wa ti odun 1999.
Won ni bi a si ti n towo bo owo ilu naa maa leyin nigba ti arun yii ba lo. Won ni ko tun ba ofin ile wa mu rara. Won ni loooto ni isuna wa fun nnkan ojiji sugbon ijoba apapo ati ijoba ipinle ko tile tele okankan alaale awon ofin naa.
Ara awon agbejoro naa ni a ti ri Ebun-olu Adegoruwa (SAN), Inibehe Effiong, Charles Omole lati U K ati bee bee lo.
Eyi si n fa ariyanjiyan pelu awon ojogbon kookan, awon ni ko si iye ti ijoba apapo ati ti ipinle na ti o po ju ti iru ajakale arun yii ba sele.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Rògbòdìyàn ẹgbẹ́ onímọ́tò Èkó n fẹ́jú kẹkẹ

Rògbòdìyàn ẹgbẹ́ onímọ́tò Èkó n fẹ́jú kẹkẹ Ọrẹ Òtítọ́jù Àwọn àgbà sọ pé ìjàngbọ̀n kìí nìka…