Home ÀKỌ̀TUN Sanwo-Olu máa fún ẹgbẹ̀rún lọ́nà igba ènìyàn lóúnjẹ l’Eko
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - March 27, 2020

Sanwo-Olu máa fún ẹgbẹ̀rún lọ́nà igba ènìyàn lóúnjẹ l’Eko

Nipa rogbodiyan ajakale arun coronavirus to n ja kaakiri agbaye to si tun ti rapala wo orileede Naijiria lati bii ose merin seyin.
Ijoba ipinle Eko ti ti awon oja ti kii se ti ounje jijie ati mimu. Awon eniyan si n yo ijoba ipinle Eko lenu pe ki o ti gbogbo ilu pa lo le segun arun naa daadaa. Sanwo-Olu da won lohun pe arun naa ko ti ran de iye to le mu ki ijoba ti gbogbo Eko nitori ipo ti ipinle naa wa ni orileede yii.
Gomina Sanwo-Olu tun salaye awon to maa letoo si ounje ofe. O ni awon ti eya ara pe nija ati awon arugbo ni eto naa koko wa fun bayii. O ni bi agbara ba se n de sii ni o maa so bi awon se maa te siwaju nipa iranlowo naa.
Bayii eniyan aadorin (70) lo ti ko arun buruku naa ti merinlelogoji (44) si sele ni ipinle Eko. Ki Eledua ba wa segun ajakale arun naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí Orílẹ̀ yìí gba ọlọ́pàá síi, kí á pèsè ohun ààbò ogun tiwantiwa–Ọsinbajo

Ó yẹ kí Orílẹ̀ yìí gba ọlọ́pàá síi, kí á pèsè ohun ààbò ogun tiwantiwa–Ọsinbajo Ọrẹ …