Home ÀKỌ̀TUN Patric Mboma pàdánù è̩gbó̩n re̩ só̩wó̩ àrùn Coronavirus

Patric Mboma pàdánù è̩gbó̩n re̩ só̩wó̩ àrùn Coronavirus

Patric Mboma pàdánù è̩gbó̩n re̩ só̩wó̩ àrùn Coronavirus

– Lati Owo Akinwale Taophic.

Agbaboolu ni igba kan ri fun orileede Cameron, ti o je oguna gbongbo ti n dato lenu igbin ti a ba n soro nipa boolu alafesegba ni ile adulawo ajaaja ni orileede abinibi re Cameron, Patrick Nboma, ti fi ibanuje okan re han lori iku okan pataki ninu ebi won ti o je aburo baba re sugbon ti o ko ipa ribiribi monigbagbe ni igbesi aye re, Achille Essome Moukouri, eni ti o je Olorun nipe latari a run COVID-19 ti o lugbade laarin ose ti o koja lo yi.

Nigba ti o n ba awon oniroyin soro lori eto gbajugbaja kan ni orileede Cameron, o so wi pe mama oun ni o pe oun lati tu ofo eni ti o je alaisi yi fun oun, eyi ti o je ibanuje okan gidigidi fun oun ati gbogbo awon ebi oun patapata.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwo̩n aké̩kò̩ó̩ WASCCE tó fi ìsekúse parí ìdánwò

Àwo̩n aké̩kò̩ó̩ WASCCE tó fi ìsekúse parí ìdánwò Yìnká Àlàbí O ma se o! Awo̩n ake̩ko̩o̩…