Home ÀKỌ̀TUN E̩ má dáké̩ àdúrà o ! àjàkálè̩ àrùn coronavirus wo̩ ìpìnlè̩ Ò̩s̩un
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - March 25, 2020

E̩ má dáké̩ àdúrà o ! àjàkálè̩ àrùn coronavirus wo̩ ìpìnlè̩ Ò̩s̩un

E má dáké̩ àdúrà o ! àjàkálè̩ àrùn coronavirus wo̩ ìpìnlè̩ Ò̩s̩un

Ìròyìn láti o̩wó̩ Yínká Àlàbí

Gbogbo igbiyanju ijoba apapo ki arun buruku yii ma tan kale lo ti fere ja si pabo tan bayii. Bi Ajo N C D C se gbiyanju to lori arun naa ni o si tan kiri ilu.
Ko si eni to mo bi arun buruku naa se tele arinrinajo Kan to sese ti ilu oyinbo de.
Eni naa wo ipinle Osun ni ijeeje. Arun naa je jade moju oni. Eledua nikan lo mo ajosepo to ti wa laarin eni naa ati ebi pelu ojulumo.
E saa je ki a kun fun adura ki imototo wa si lekele kan sii.
Arun buruku yii gan-an ti mi ijoba apapo titi. Ko je ki opo mo odo to maa da orunla si mo.
Eyi mu ki apapo awon ti ni arun naa ni Naijiria wo merindinlaadota (46).

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Nítorí ẹ̀sùn ìfipábánilòpọ̀, àwọn aláṣẹ Fásitì KWASU lé olùkọ́ kan dànù

Nítorí ẹ̀sùn ìfipábánilòpọ̀, àwọn aláṣẹ Fásitì KWASU lé olùkọ́ kan dànù Ọrẹ Òtítọ́jù Àwọn …