Home ÀKỌ̀TUN Àrùn Coronavirus kò lè kú – Pastor Adébóyè
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - March 22, 2020

Àrùn Coronavirus kò lè kú – Pastor Adébóyè

Àrùn Coronae̩irus kò lè kú – Pastor Adébóyè
Ìròyìn láti o̩wo̩ Yínká Àlàbí

Oludari ijo Redeemed patapata, Alagba Adejare Adeboye ni ajakale arun Corona ko le pare patapata.
O ni arun naa kan maa fara pamo die ni nitori pe Olorun ti fi han oun pe aisan nla bee maa be sile ti o si maa fere kari aye.
Baba ni awa omo eniyan ni a ni lati sun mo Olorun ki a si wa idariji ese.
Alagba Adeboye n salaye yii ni ibi ijosin to waye lonii ni telifison Dove ninu DSTV. Eyi waye bee lati tele ofin ti ijoba ipinle ati ijoba apapo se nipa pe ki eniyan ma se le ni aadota ni ipejo kankan.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn wọ̀nyí ti kékeré dèrò ẹ̀wọ̀n, jìbìtì orí ayélujára ló kó bá wọn

Àwọn wọ̀nyí ti kékeré dèrò ẹ̀wọ̀n, jìbìtì orí ayélujára ló kó bá wọn Ọrẹ Òtítọ́jù Àwọn ló …