Home ÀKỌ̀TUN Peter Fatomilola ní àìsí ẹ̀kọ́ ń mú káwọn òṣèré tíátà ó máá ṣe oun tí kò tọ́
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - March 21, 2020

Peter Fatomilola ní àìsí ẹ̀kọ́ ń mú káwọn òṣèré tíátà ó máá ṣe oun tí kò tọ́

Peter Fatomilola ní àìsí ẹ̀kọ́ ń mú káwọn òṣèré tíátà ó máá ṣe oun tí kò tọ́.

Fẹ́mi Akínṣọlá

Ṣé Yorùbá bọ̀ wọ́n ní báyé bá tojú àgbà bàjẹ́, àìmọ̀wàáhù wọn ní. Èyí ló díá fún bí àwọn tọ́rọ̀ kàn lágboolé òṣèré e tíátà se ń lọgun tantan pé,láyé ọjọ́sí, eré ìtàgé jẹ́ gbajúgbajà láwùjọ àwọn onítíátà lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà.

Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn Ọ̀jọ̀gbọ́n léré tíátà ló sì ti ń pariwo pé eku kò ké bí eku mọ́ lórí ipa tí tíátà ń kó lórí ìdàgbàsókè àwùjọ.

Alàgbà Peter Fátómilọ́lá, ọ̀kàn lára àwọn òdú eléré tíátà lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà, t’óun pẹ̀lú kópa lásìkò eré ìtàgé ṣàlàyé ohun tó ṣẹlẹ̀ àti ìbí tí ọ̀rọ̀ ti wọ́ wá.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí Orílẹ̀ yìí gba ọlọ́pàá síi, kí á pèsè ohun ààbò ogun tiwantiwa–Ọsinbajo

Ó yẹ kí Orílẹ̀ yìí gba ọlọ́pàá síi, kí á pèsè ohun ààbò ogun tiwantiwa–Ọsinbajo Ọrẹ …