Home ÀKỌ̀TUN Ọ̀nà Jìbìtì 2
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - March 19, 2020

Ọ̀nà Jìbìtì 2

Ọ̀nà Jìbìtì 2
Awon miiran maa n duro si opopona bi eni ti moto won baje. Won le mu omo ileewe kan tabi meji si egbe won gege bi eni to nilo iranlowo. Awon to ba duro ti won ti ko mo won rii, ti won woo pe iru aso ile-iwe omo awon lo wa lorun awon to wa legbee moto ni won maa n se lose.
Eyi ko ni ki a ma se se aanu. Eledua tile nife si eni to ba n ran omolakeji re lowo. Imoran IROYIN OWURO ni pe ki a wo ibi to ba dara ti a ti le nilo iranlowo ki a to se iru oore bee tabi ki a wa awon agbofinro to ba wa nitosi fun iru iranlowo bee.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Okorocha ketí ikún sí ìpé làwọn fi ṣígun kàá mọ́lé mọ́lé-EFCC

Wọ́n ní Okorocha ketí ikún sí ìpé làwọn fi ṣígun kàá mọ́lé mọ́lé Ọrẹ Òtítọ́jù Àjọ tó ń gbó…