Home Orisirisi Alárùn kòkòrò corona e̩lé̩è̩ké̩ta fara hàn
Orisirisi - March 17, 2020

Alárùn kòkòrò corona e̩lé̩è̩ké̩ta fara hàn

Alárùn kòkòrò corona e̩lé̩è̩ké̩ta fara hàn
Ìròyìn láti o̩wó̩ Yínká Àlàbí

Arabinrin ti o sese ti ilu London de ni o bere si nii wuko ti o si n se kata. Ni eyi ti o mu ki o fara re sile fun ayewo coronavirus.
Nigba ti esi ayewo jade ni won rii pe o ti ko arun naa. Eyi si mu ki itoju ti o peye bere fun un ni ilu Yaba to wa ni ipinle Eko.

Check Also

Rògbòdìyàn ẹgbẹ́ onímọ́tò Èkó n fẹ́jú kẹkẹ

Rògbòdìyàn ẹgbẹ́ onímọ́tò Èkó n fẹ́jú kẹkẹ Ọrẹ Òtítọ́jù Àwọn àgbà sọ pé ìjàngbọ̀n kìí nìka…