Home ÀKỌ̀TUN Ọba mẹ́wàá, ìgbà mẹ́wàá
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - March 10, 2020

Ọba mẹ́wàá, ìgbà mẹ́wàá

Awon onpitan wu itan Emir Kano ana jade. Won ni oro re dabi egun ti baba baba re ti se sile. Won ni odun 1963 ni ede aiyede waye laare Emir Mohammed Sanusi to je baba eni ti gomina yo ni ana yii pelu Amenh Oboni ti ilu Igala.
Rogbodiyan yii naa ni o yo baba Sanusi ana kuro lori oye. Odun ketadinlogota naa ree bi ana, ti gomina Gaduje tun yo Emir Sanusi kuro bi eni yo jiga. Loju ese naa ni won fi omo Aminu Ado Bayero dipo re.
Orisiirisii esun ni ijoba ipinle Kano fi kan Emir Sanusi, won ni o se owo rogunrogun kan maku maku ti ko si alaye gidi Kankan lori re. Won ni ko ki n gboro si ijoba ipinle naa lenu rara. Gbogbo eyi ni won ko po ti ijoba ipinle naa fi ni osuwon re ti kun.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí Orílẹ̀ yìí gba ọlọ́pàá síi, kí á pèsè ohun ààbò ogun tiwantiwa–Ọsinbajo

Ó yẹ kí Orílẹ̀ yìí gba ọlọ́pàá síi, kí á pèsè ohun ààbò ogun tiwantiwa–Ọsinbajo Ọrẹ …