Home ÀKỌ̀TUN Àwo̩n o̩mo̩ Nàìjíríà fajúro sí ìsinmi ilé-ìgbìmò̩ asòfin
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - March 3, 2020

Àwo̩n o̩mo̩ Nàìjíríà fajúro sí ìsinmi ilé-ìgbìmò̩ asòfin

Àwo̩n o̩mo̩ Nàìjíríà fajúro sí ìsinmi ilé-ìgbìmò̩ asòfin
Ìròyìn láti o̩wó̩ Yínká Àlàbí

Ariyanjiyan to gbopan waye ni ile-igbimo asofin kekere ni aaro oni. Ariyanjiyan naa waye lori eto aabo to mehe ati arun buruku ti gbogbo aye n pe ni coronavirus to gbile ni orileede China.
Ile igbimo yii ni awon n lo fun isinmi olose meji lati le loo roo daadaa bi awon se maa gbogun ti isoro Naijiria.
Aba yii ko ba laakaye opo omo ilu yi lo, won ni o ye ki won duro lati fun ijoba apapo lorun lori ona abayo fun awon isoro yii. Won ni ko ye ki won sinmi lasiko ti isoro ilu n gbona janjan bayii.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Bí ẹgbẹ́ òṣèlú ù mi bá fàmí kalẹ̀, ìyókù sẹ́pẹ́rẹ́—Tinubu

Bí ẹgbẹ́ òṣèlú ù mi bá fàmí kalẹ̀, ìyókù sẹ́pẹ́rẹ́—Tinubu Ọrẹ Òtítọ́jù Olùdíje fún i…