Home ÀKỌ̀TUN Ẹ pa ìrìnàjò sí ilẹ̀ China tì báyìí – Aare Buhari
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - January 30, 2020

Ẹ pa ìrìnàjò sí ilẹ̀ China tì báyìí – Aare Buhari

Ẹ pa ìrìnàjò sí ilẹ̀ China tì báyìí – Aare Buhari
Láti ọwọ́ Yínká Àlàbí

“koju maa ribi, gbogbo ara ni oogun re”. Eyi lo mu ki ile ise Aare Naijiria parowa si gbogbo omo ilu pe ki won ma se lo si orileede China bayii nitori arun CORONAVIRUS ti o n ba won ja ni ilu naa.
Arun ti ko gboogun ni arun yi, bi o se n pa kukuru, ni o pa n pa giga, bi o se n pa okunrin lo n pa obinrin. Arun yii ko mo onile bee ni ko mo alejo.
Arun buruku yii ti je ki eto aabo gbogbo orileede ni agbaye nipon gan-an. Ayewo finni-finni ni ki onile ati alejo to le wo orileede kankan ni agbaye bayii.
Awon onimo ilera naa tun gba gbogbo eniyan niyanju lati jinna si awon eran bii eku, adan ati awon eya won, nitori iwadii fihan pe ara awon eranko yii ni awon eniyan ti n ko aisan buruku naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ọwọ́ pálábá adigunjalè ẹlẹ́nimẹ́ta tó ja Tọpẹ Alabi lólè owó ṣégi

Ọwọ́ pálábá adigunjalè ẹlẹ́nimẹ́ta tó ja Tọpẹ Alabi lólè owó ṣégi Ọrẹ Òtítọ́jù Ọjọ́ gbogbo…