Home ÀKỌ̀TUN Ò̩dàle̩ ni àwo̩n asojú tó darapò̩ mó̩ e̩gbé̩ APC – Kola Ologbondiyan
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - January 29, 2020

Ò̩dàle̩ ni àwo̩n asojú tó darapò̩ mó̩ e̩gbé̩ APC – Kola Ologbondiyan

Ò̩dàle̩ ni àwo̩n asojú tó darapò̩ mó̩ e̩gbé̩ APC – Kola Ologbondiyan
Láti o̩wó̩ Yínká Àlàbí
Akowe agba fun olori egbe oselu alatako ni orileede yii, alagba Kola Ologbondiyan ni o n ba awon oniroyin soro ni oni, nigba ti o gbo pe awon omo egbe oselu awon ti won je asoju ni ipinle Imo ti dara po mo egbe APC.
O ni onijekuje ati odale ti ko ni afarada rara ni awon asoju naa. O ni nitori pe egbe oselu APC jawe olubori ni ile ejo ti yaa mu ki awon asoju yii ya lo si egbe oselu to jawe olubori. O ni o tumo si pe “eyele tiwon maa n ba onile je, ba onile mu, ti o ba wa di ojo iku, won a yeri”.
Ologbondiyan ni awon asoju yii ko dara lawujo rara.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí Orílẹ̀ yìí gba ọlọ́pàá síi, kí á pèsè ohun ààbò ogun tiwantiwa–Ọsinbajo

Ó yẹ kí Orílẹ̀ yìí gba ọlọ́pàá síi, kí á pèsè ohun ààbò ogun tiwantiwa–Ọsinbajo Ọrẹ …