Home ÀKỌ̀TUN Ààbò ìlú Nàìjíríà mé̩he̩ – ilé ìgbìmò̩ asòfin
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - January 29, 2020

Ààbò ìlú Nàìjíríà mé̩he̩ – ilé ìgbìmò̩ asòfin

Ààbò ìlú Nàìjíríà mé̩he̩ - ilé ìgbìmò̩ asòfin

Ààbò ìlú Nàìjíríà mé̩he̩ – ilé ìgbìmò̩ asòfin
Láti o̩wó̩ Yínká Àlàbí
Ejo kii se ejo ara eniyan ki a maa moo da. Eyi lo difa fun awon omo ile igbimo asofin agba ti won fi ni oro aabo ni nnkan akoko ti awon maa koko ye wo.
Won n pete pero lori ojo ti Muhammad Adamu to je oga olopaa patapata ni orileede yii maa wa foju han ni ile igbimo naa.
Won ni awon ni lati jo jokoo yii tabili po ki awon le mo odo ti awon maa da orunla si. Won ni oloju ko ni laju re sile ki talubo woo.
Yoruba bo, won ni “agbara ko ni ohun ko nile wo, onile ni ko ni gba fun un”.
Won ni awon ajinugbe ti won n da ilu ru yii ko tii deyin leyin Naijiria. Inu ki ilu daru ni awon wa ni gbogbo ojo aye won.
Awon ile igbimo asofin ni afaimo ki awon eya to ku naa ma se ko ise eya Yoruba “AMOTEKUN “. Won ni nigba ti eto ti wa Nile lati ni olopaa ipinle ati ipinle ni eyi to maa le segun awon obayeje. Se ajide bi Oyo naa laa ri, Oyo ko ni se bi enikookan.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Rògbòdìyàn ẹgbẹ́ onímọ́tò Èkó n fẹ́jú kẹkẹ

Rògbòdìyàn ẹgbẹ́ onímọ́tò Èkó n fẹ́jú kẹkẹ Ọrẹ Òtítọ́jù Àwọn àgbà sọ pé ìjàngbọ̀n kìí nìka…