Dáńfó, Ò̩kadà, Tòkunbò̩ àti àwo̩n ò̩rò̩ Nàìjíríà míràn wo̩ inú Díkísó̩nárì Òyìnbó
Dáńfó, Ò̩kadà, Tòkunbò̩ àti àwo̩n ò̩rò̩ Nàìjíríà míràn wo̩ inú Díkísó̩nárì Òyìnbó
Láti o̩wo̩ Yínká Àlàbí
Bi aye se n yi naa ni gbogbo ohun to wa ninu re naa n yi. Awon Oyinbo lo woye pe ede Oyinbo ni a n so ju ni Naijiria, a si ni ero to le ni milionu igba, ni eyi ti o mu ki won se agbeyewo re daadaa. Won si sa oro mokandinlogbon(29 words) ninu ede Naijiria. Won to gbogbo re si inu iwe atumo won ti a mo si Oxford Learners Dictionary.
Ti a ba ti sii de abala B ni e ti maa ri awon oro bii “barbing saloon, bike, bukataria” abala C maa fun wa ni ” chop-chop” abala D maa fun wa ni “danfo” abala E maa fun wa ni “ember months ” ati bee bee lo.
Gbogbo awon oro yii ni won si ni itumo to se regi ninu iwe atumo won.
Rògbòdìyàn ẹgbẹ́ onímọ́tò Èkó n fẹ́jú kẹkẹ
Rògbòdìyàn ẹgbẹ́ onímọ́tò Èkó n fẹ́jú kẹkẹ Ọrẹ Òtítọ́jù Àwọn àgbà sọ pé ìjàngbọ̀n kìí nìka…