Home ÀKỌ̀TUN Valencia fìyà je̩ Barcelona lójú Coach tuntun

Valencia fìyà je̩ Barcelona lójú Coach tuntun

Valencia fìyà je̩ Barcelona lójú Coach tuntun
Láti o̩wó̩ Yínká Àlàbí
Ojo ogun le fun iko agbaboolu Barcelona laipe yii nigba ti egbe agbaboolu Valencia gbo ewuro si won loju pelu ami ayo meji, ti won ko si le da okankan pada.
Barcelona gbiyanju gan-an ni abala akoko idije naa, koda penariti ti o ye ki Valencia koko gba wole ni asole won,Ter Sergen ko je ko wole.
Gbogbo ija ni iko Valencia gbe lo si ibi ere boolu naa, eyi lo mu ki Maxi Gomez gba ona miran yo. O si je ami ayo meji ni abala keji idije naa.
Eyi ti o dun awon ololufe iko Barcelona ni akoni-moogba tuntun ti won sese gba, Queien Setien.
Eyi ni idije akoko ti Setien maa gba.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Bí ẹgbẹ́ òṣèlú ù mi bá fàmí kalẹ̀, ìyókù sẹ́pẹ́rẹ́—Tinubu

Bí ẹgbẹ́ òṣèlú ù mi bá fàmí kalẹ̀, ìyókù sẹ́pẹ́rẹ́—Tinubu Ọrẹ Òtítọ́jù Olùdíje fún i…