Home ÀKỌ̀TUN E̩ fé̩ ìyàwó méjì tàbí kí e̩ fi è̩wò̩n jura – Eritrea
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - January 19, 2020

E̩ fé̩ ìyàwó méjì tàbí kí e̩ fi è̩wò̩n jura – Eritrea

E̩ fé̩ ìyàwó méjì tàbí kí e̩ fi è̩wò̩n jura – Eritrea
Láti o̩wó̩ Yínká Àlàbí
lu ti ko sofin, ese ko si nibe”. Ijoba orileede Eritrea ti soo dofin bayii pe awon okunrin ibe gbodo ri daju pe awon fe iyawo meji tabi ju bee lo.
Ijoba ni awon ti setan lati se iranlowo nibi ti o ba ti ye bii owo inawo, ibi inawo ati awon nnkan miiran ti agbara okunrin naa ko ba ka.
Ofin naa de awon obinrin kookan ti won je alara gbigbona pe won ko gbodo lodi si ofin yii. Ijoba ni obinrin to ko ba tun gba ki oko re fe ekeji naa maa fewon jura.
Iwadii IROYIN OWURO lori ofin yii ni pe ogun kan be sile lodun 1998 titi de 2000 laarin orileede naa ati Ethioia,ni eyi ti o mu ki orileede naa padanu okunrin egberun lona aadojo (150,000).
Eyi je ki aaye yi si sile ti opo obinrin wa di alaini oko mo. Gbogbo orileede yii gan-an tele kogun to de ko ju milionu merin lo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Okorocha ketí ikún sí ìpé làwọn fi ṣígun kàá mọ́lé mọ́lé-EFCC

Wọ́n ní Okorocha ketí ikún sí ìpé làwọn fi ṣígun kàá mọ́lé mọ́lé Ọrẹ Òtítọ́jù Àjọ tó ń gbó…