Home ÀKỌ̀TUN Ikú yo̩wó̩ Lekan Are̩ láwo
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - January 18, 2020

Ikú yo̩wó̩ Lekan Are̩ láwo

Iku yowo Alagba Lekan Are lawo
Ko si bi eniyan to dara ti dagba to, araye ki i fe ki won tete lo je ipe Eledua. “Awaye i ku kankan ko si”, leyin aisan ranpe iku yowo Alagba Lekan Are lawo.
Alagba yii kan saisan ranpe ni won ba gbe won lo si ile iwosan University Teaching Hospital (UCH) to wa ni ilu Ibadan. Ibe naa ni Olojo de ba won gege bi Omowe Wale Babalakin se kede saye.
Lekan Are gba oye OON lowo ijoba apapo nibi ti won lokiki to.
Awon ni Aare GCIOBA nigba aye won.Awon tun ni Patron Government College Ibadan Old Boys Association, Ibadan.
Awon ni Alaga Kakanfo Inn and Conference Centre ni Ibadan.
Ojo kewaa osu yii ni baba yii pe omo odun merindinlaadorun-un (86years) loke eepe ki iku to pa oju won de ni oni ojo kejidinlogun.
Ki Eledua ba wa dele fun eni rere.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Okorocha ketí ikún sí ìpé làwọn fi ṣígun kàá mọ́lé mọ́lé-EFCC

Wọ́n ní Okorocha ketí ikún sí ìpé làwọn fi ṣígun kàá mọ́lé mọ́lé Ọrẹ Òtítọ́jù Àjọ tó ń gbó…