Home orisiirisii Às̩o̩té̩lè̩ Father Mbaka se̩ lórí gómìnà ìpínlè̩ Imo
orisiirisii - Orisirisi - January 14, 2020

Às̩o̩té̩lè̩ Father Mbaka se̩ lórí gómìnà ìpínlè̩ Imo

Às̩o̩té̩lè̩ Father Mbaka se̩ lórí gómìnà ìpínlè̩ Imo
Láti o̩wó̩ Yínká Àlàbí
Bi a da ogun odun, a pe, bi a da ogbon osu a ko ni idajo ti o ti n tiri bi omo ojo se waye lonii.
Idajo naa waye laarin gomina Emeka Ihedioha ti egbe oselu PDP ati Ogbeni Hope Uzodinma ti egbe oselu APC.
Adajo ni ki Uzodinma lo ni ipo gomina ipinle naa, o si fi ofin de Ihedioha gege bii gomina.
Ijo ati ilu gba ipinle naa Kan lati odo awon ololufe eni to jawe Olubori naa.
Eyi mu ki awon eniyan tee ranti ara asotele gbaju-gbaja osise Olorun ti gbogbo eniyan mo si Reverend Ejike Mbaka. Won ni Mbaka ti soro naa tele pe Uzodinma lo maa je gomina ipinle naa, bi o tile je pe eni bi go.ina Ihedinma ninu die, Ojise Olorun ni oun ti oun ti ni oun so.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí Orílẹ̀ yìí gba ọlọ́pàá síi, kí á pèsè ohun ààbò ogun tiwantiwa–Ọsinbajo

Ó yẹ kí Orílẹ̀ yìí gba ọlọ́pàá síi, kí á pèsè ohun ààbò ogun tiwantiwa–Ọsinbajo Ọrẹ …