Home ÀKỌ̀TUN Soyinka àti àwo̩n Ò̩jò̩gbó̩n míràn kìlò̩ ogun abé̩lé
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - January 13, 2020

Soyinka àti àwo̩n Ò̩jò̩gbó̩n míràn kìlò̩ ogun abé̩lé

Soyinka àti àwo̩n Ò̩jò̩gbó̩n míràn kìlò̩ ogun abé̩lé
Láti o̩wó̩ Yínká Àlàbí

Wole Soyinka ati awon Ojogbon miiran seranti ogun abele aadota odun seyin
Ojogbon Wole Soyinka to gba ami eye litireso to ga ju ati awon Ojogbon miiran ni won ko ara won jo ti won si n se ikilo fun omo Naijiria.
Won ni ogun ko da bi iyan, ogun ko da bi eko koda won ni ko jo iresi. Won ni ki onikaluku so ewe agbeje mowo.
Won ni gbogbo awon eniyan ti won jeun yo tan ti won wa n fi orin ogun tayin lo sora won gidi.
Won ni aadota odun naa lo dabi ana yii. Won ni gbogbo igbese to ba ye ni ki ijoba ati awon alenu loro ni ilu gbe ti ko fi ni si ogun tabi ija ni ilu.
Ara awon “omoran tii moyun igbin ninu ikarahun” ni Ojogbon Pat Utomi, Ojogbon Anya Anya ati awon miiran ni oro ogun abele to koja soju awon daadaa ni, kii se pe awon kaa ninu iwe tabi wo fidio re.
Awon Ojogbon yii pe oruko egbe won ti kii se ti ijoba tabi oselu ni ” never again “. Eyi tumo si pe “ko tun gbodo waye mo”.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Rògbòdìyàn ẹgbẹ́ onímọ́tò Èkó n fẹ́jú kẹkẹ

Rògbòdìyàn ẹgbẹ́ onímọ́tò Èkó n fẹ́jú kẹkẹ Ọrẹ Òtítọ́jù Àwọn àgbà sọ pé ìjàngbọ̀n kìí nìka…