Home ÀKỌ̀TUN O̩dún 2019 kò dára rárá fún eré ìdárayá Nàìjíríà – Rafiu Ladipo
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - January 13, 2020

O̩dún 2019 kò dára rárá fún eré ìdárayá Nàìjíríà – Rafiu Ladipo

O̩dún 2019 kò dára rárá fún eré ìdárayá Nàìjíríà – Rafiu Ladipo
Láti o̩wó̩ Yínká Àlàbí
Alagba Rafiu Ladiipo lo n ba awon oniroyin soro pe odun to koja ko dara rara fun ere idaraya orileede yii.
Rafiu Ladipo ni Aare awon egbe alafeyinti ere idaraya paapaa julo ere boolu gbigba.
Alagba yii ni gbogbo ere idaraya ni awon ti maa n se afeyinti fun orileede yii sugbon ibi ti opo wa ti mo won ti a ti n ri won ju ni ibi ere boolu gbigba.
Alagba Ladiipo ni ikuna odun to koja ti po ju, o ni o bere lati ori awon oje wewe Super Eaglet, Fly Eagles, Super Eagles ati awon Super Falcons.
Alagba yi ni ipo keta ti Super Eagles se ni ibi ife eye Adulawo lo fere maa je aseyori to wo orileede yii lodun to koja.
Alagba Ladiipo gba ijoba apapo lamoran pe “lati okeere ni oloju jinjin tii makin sun” ni ki won se oro ere idaraya orileede yii. O ni ki won je ki a tete bere si ni gbaradi fun gbogbo idije to ba wa lodun yii. Ki won ma si se fi eto enikankan dun un. Eyi lo le je ki a kese jari pelu aseyori ti ko legbe.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Bí ẹgbẹ́ òṣèlú ù mi bá fàmí kalẹ̀, ìyókù sẹ́pẹ́rẹ́—Tinubu

Bí ẹgbẹ́ òṣèlú ù mi bá fàmí kalẹ̀, ìyókù sẹ́pẹ́rẹ́—Tinubu Ọrẹ Òtítọ́jù Olùdíje fún i…