Home ÀKỌ̀TUN Ó dèèwo̩ f’ó̩kùnrin lati gun kè̩ké̩ e̩lé̩se̩ mè̩ta pè̩lú obìnrin – Gaduje
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - December 27, 2019

Ó dèèwo̩ f’ó̩kùnrin lati gun kè̩ké̩ e̩lé̩se̩ mè̩ta pè̩lú obìnrin – Gaduje

Ó dèèwo̩ f’ó̩kùnrin lati gun kè̩ké̩ e̩lé̩se̩ mè̩ta pè̩lú obìnrin – Gaduje
Yinka Alabi
Gomina ipinle Kano, Alhaji Umar Gaduje lo soo dofin nibi idanilekoo awon Musulumi kan to waye ni ipinle naa.
O ni lati odun 2020 to n bo, okunrin kankan ko gbodo wo keke Marwa tabi Keke Napep pelu obinrin kankan ni ipinle Kano.
Gomina salaye siwaju sii pe , ipinle Musulumi ti awon eniyan fi n se awokose ni ilu Kano, awon ko si gbodo yinge ninu gbogbo nnkan daadaa ti aye mo awon si. O ni nipa idi eyi enikeni to ba ru ofin lati ojo kin-in-ni osu kin-in-in odun to n bo yoo rugi oyin.
Gaduje ni agbere bere lati ara fifi ara ko ara lati inu keke, ni eyi ti Olorun lodi si gidigidi.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ilé ẹjọ́ tú el-zakzaky àti ìyàwó rẹ̀ sílẹ̀

Ilé ẹjọ́ tú el-zakzaky àti ìyàwó rẹ̀ sílẹ̀ Fẹ́mi Akínṣọlá Ajá tó relé ẹkùn tó bọ̀,ó tọ́ kí…