Home ÀKỌ̀TUN Àhes̩o̩ ò̩rò̩ ni ikú Babangida
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - December 15, 2019

Àhes̩o̩ ò̩rò̩ ni ikú Babangida

Aheso oro ni iku Babangida
Yinka Alabi
Ariwo iku ajagunfehinti to o tun je Aare Ologun ni orileede yii tele ri, Ibrahim Babangida ni o gbode Kan.
Ariwo yii po lori ero ayelujara lati idaji oni sugbon Ogbeni Kazim Afegbua ni iro ni.
O ni koko ti ara ota n le ni ara oga oun le. O ni loooto ni ara ti di ara agba fun Babangida sugbon eni ti Olorun ko pa, ko le ku.
Olowo otun Babangida ro awon eniyan ki ma se tele awon iroyin eleje ti won Kan maa n gbe gbogbo ohun toju ko to kiri.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí Orílẹ̀ yìí gba ọlọ́pàá síi, kí á pèsè ohun ààbò ogun tiwantiwa–Ọsinbajo

Ó yẹ kí Orílẹ̀ yìí gba ọlọ́pàá síi, kí á pèsè ohun ààbò ogun tiwantiwa–Ọsinbajo Ọrẹ …