Home ÀKỌ̀TUN Akpabio fajúro sí owó ìnákúùná Niger Delta
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - October 29, 2019

Akpabio fajúro sí owó ìnákúùná Niger Delta

Akpabio fajuro si owo inakuna Niger Delta
Lati owo
Yinka Alabi
Ijoba apapo ti Senato Akpabio n soju fun lo ti gbanaje lori awon ise ajanbaku to n waye ni agbegbe Niger Delta.
Akpabio ni o ye ki ise ijoba maa te siwaju bi ijoba se n yi pada ni amo o ni ko ri bee ni oro orileede yii. O ni bi eto ijoba se n yi pada ni awon eniyan bere si ni seto owo miran fun ise miran. Won wa n pa ise ti awon Kan ti se ti.
Akpabio ni eyi ni lati dawo duro nitori pe owo rogun rogun ni ijoba apapo n ya soto fun agbegbe naa ni odoodun.
Akpabio ni owo ina apa yii ti bere lati bii odun metalelogun seyin bayii. O ni awon ara agbegbe naa si n pariwo pe ijoba n ri owo ni agbegbe awon bee ni ijoba naa ko sise si agbegbe naa.
Eyi wa lara ohun to da omi tutu si okan Senato Akpabio.
Lara itesiwaju agbegbe naa lo mu ki ipade pajawiri waye ni Abuja laarin awon gomina agbegbe naa pelu Aare Mohammadu Buhari lonii.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí Orílẹ̀ yìí gba ọlọ́pàá síi, kí á pèsè ohun ààbò ogun tiwantiwa–Ọsinbajo

Ó yẹ kí Orílẹ̀ yìí gba ọlọ́pàá síi, kí á pèsè ohun ààbò ogun tiwantiwa–Ọsinbajo Ọrẹ …