Home ÀKỌ̀TUN Chris Ngige fèsì lórí ìyànṣẹ́lódì tí àwọn òṣìṣẹ́ fẹ́ gùnlé
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - October 5, 2019

Chris Ngige fèsì lórí ìyànṣẹ́lódì tí àwọn òṣìṣẹ́ fẹ́ gùnlé

Chris Ngige fèsì lórí ìyànṣẹ́lódì tí àwọn òṣìṣẹ́ fẹ́ gùnlé. Àwọn òṣìṣẹ́ fèsì; ẹ ti súnwa kàngiri

Fẹ́mi Akínṣọlá

“`Ṣé sún sùn sún ewúrẹ́,ògiri lòpin rẹ̀.
Ọdún tó kọjá ni àwọn òṣìṣẹ́ ti ń
bèèrè fún ẹgbẹ̀rún lọ́nà ọgbọ̀n Naira gẹ́gẹ́ bí gbèdéke owó osù òṣìṣẹ́.
Minisita fun ọrọ òṣìṣẹ́ ati igbanisisẹ, Chris Ngige ti ni adinku yoo ba àwọn òṣìṣẹ́ lorilẹede
Naijiria k’íjọba le san owo osu awọn òṣìṣẹ́.
Nigige sọ eyi fun awọn adari ajọ òṣìṣẹ́, NLC ni Abuja lasiko ti wọn se abẹwo si i.

Ó ni ọọdunrunlelọgọrin biliọnu Naira ni ijọba nilo lati le fi san gbèdéke owo osu awọn òṣìṣẹ́, eleyii to ni o soro fun ijọba lati san pẹlu ọrọ aje to dẹnukọlẹ.
Àmọ, àwọn òṣìṣẹ́ ti fariga o, pe onyẹ kan ko gbọdọ yẹ gbedeke owo osu òṣìṣẹ́.
Ọjọkejidinlogun, Osu Kẹrin ni Aarẹ Muhammadu Buhari bu ọwọ lu òfin to rọ mọ igbeleke owo osu òṣìṣẹ́.“`

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí Orílẹ̀ yìí gba ọlọ́pàá síi, kí á pèsè ohun ààbò ogun tiwantiwa–Ọsinbajo

Ó yẹ kí Orílẹ̀ yìí gba ọlọ́pàá síi, kí á pèsè ohun ààbò ogun tiwantiwa–Ọsinbajo Ọrẹ …