Home ÀKỌ̀TUN Òmìnira yin ti dé – Buhari
ÀKỌ̀TUN - iroyin - orisiirisii - Orisirisi - October 1, 2019

Òmìnira yin ti dé – Buhari

Aare orileede yii, Alhaji Mohammed Buhari lo n fi gbogbo omo Naijiria lokan bale pe irorun ti de.
Nibi ayeye ikini ku odun ominira ti Naijiria fi pe odun mokandinlogota ni Aare ti n salaye yii.
Aare ni eyi ni o je ki ijoba apapo da ajo ati ile-ise miran to maa da lori ” lile ise wo igbe, fifi oju to isele pajawiri, ipese ounje fun awon akekoo,pipese ile olowo pooku ati bee bee lo ” sile.
Aare Buhari ni ki eto naa le kese jari daadaa lo je ki ijoba apapo fi igbakeji Aare sibe, Ojogbon Yemi Osinbajo.
Aare wa ro awon ara ilu fun ifowo-sowo-po ki gbogbo eto naa le kese jari ni irorun.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Rògbòdìyàn ẹgbẹ́ onímọ́tò Èkó n fẹ́jú kẹkẹ

Rògbòdìyàn ẹgbẹ́ onímọ́tò Èkó n fẹ́jú kẹkẹ Ọrẹ Òtítọ́jù Àwọn àgbà sọ pé ìjàngbọ̀n kìí nìka…